IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI!

by

— Lati Tiwantiwa@yahoogroups.co.uk, “Iyaafin Yeye Akilimali Funua
Olade” so:

IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI
Lati Owo Iyaafin Yeye Akilimali Funua Olade
Akoko iru e lati The Sun Newspaper Thursday Nov. 27 2003 Pg 39

Ni ti temi mo ni igbagbo wipe ojise olorun chris okotie ni o to
gbangba sun loye ni ode oni (mmo fe kio di mimo wipe emi kii se omo
ijo re, ile isisn miran ni mo nlo) kin ni obi oro yii? Emi alawo
dudu
tii se omo bibi orile ede Amerika tio yan orile ede Naijiria laayo
bi
ilu abinibi re lati bii odun meedogbon. Nitori ohun nikan ni ogun
nagbongbo ojise olorun tio tako atankale asakasa ibalopo laarin
okunrin si okunrin ni orile ede yii. Ojise olorun yii, ni o se ikilo
fun wa ni odun 2002 wipe “ibalopo okunrin sokunrin tin gbogbo
kaakiri’ (Ninu iwe iroyin The new Treasure Magazin ni ojo
kokanlelogun titide ikerindinlogun (odun Alumoni) tio jade ninu osu
agemo ni oju ewe kewa de ikeedogun. Bakanna ninu iwe re The Last
Outcast Ojise Olorun yii kan na ni won so fun mi pe ni igb ekeji
tio
se tako ibalopo laarin obinrin sobinrin gegebi ohun ija esu adun
koko
moni.

Pupo omo orile ede yii ti mo ba fi oro jomitoro oro lori iwa ibaje
ko
tile ni igbagbo wipe asakasa yii nbe lawujo wa latari wipe awon
alawo
funfun nikan ni ibaje yi gbewo bi ewu. Sugbon iwakiwa yii n se jamba
gbemigbemi fun opolopo idi le le yi ti igbehin re silee so gbogbo
awon orile ede wa si oko iparun.
“Orisirisi awon iwe iroyin wa gbogbo ni onse afihan asa buburu yii
bere latori iwe iroyin Fame okiki ojo ojo kerin osu owada (Sept.) ni
odun 2002 pelu akole “Lesbian in Lagos State house (Ibalopo Obinrin
sobinrin ni ilu eko.
Bakanna iwe ikroyi City People (olaju Eniyan) ti ojo keedogun osun
sawere (October) ni odun 2003 pelu akole “Abuja Lesbians Forum Club”
(Alabanilopo laarin obinrin sobinrinAbuja da egbe sile) Eyi si je
ategun fun awon olori ile iwe giga lobinrin lati maafa awon akeko
won
obinrin sinu egbe yii. Iroyin yii jeyo ninu iwe iroyin Sunday
Vanguard to ojo keedogun osu okudu ti odun2003 ni oju ewe
kejilelogun
titi de ikefalelogun (June 15, 2003 P22-23) lati mu iwa ibaje yi wa
sopin ni akoko gbogbo.
Obinrin orile ede yii gbodo doju ija ko iwakiwa yii pelu orisirisi
ona bii adura gbigba gbogbo idile, Ile Iwe papa julo ile iwe
onibagbe
akeko, ipade oluko ati awon obi ati awon omo ile ijosin gbogbo
musulumi ati awon omolehin jesu gbogbo ni Atari wipe iwakiwa yii le
bi orile ede yi wo patapata nipase awon omo wa.

Gbogbo iya gbodo mu eko nipa ibalopo ni okunkundun fun awon omo
won “o gbodo je mimo fun awon omo wa wipe mimo ni eya abe won eyi ti
enikeni ko gbodo se oun kohun pelu je.
Kinidi? Idi eyi ni wipe awon ogo were ode oni awon ore, oga, ati
alabagbe won fa si inu iwakiwa yii (Fun apere iwe iroyin city people
ojo keedogun osu okudu ti odun 2003 ni oju ewe kerinla) se afihan bi
omo odun mefa se di ara awon oniwakuwa yi pelu akole “How I became a
homosexual” (Bi mo se di alabalopookunrin sokunrin)
Gbogbo onise iroyin ni orile ede yii gbogbo gbaradi lati maa tu
asiri
opolopo awon iwakiwa yii awon naa si gbodo gbogun ti iwa ibaje yii
lati lodi si wiwa enikeji fun awon oniwakiwa yii nipase iwe iroyin.

Idun koko moni iwakiwa yii tile poju to aarun Ibalopo kogboogun
AIDS
Ni ayaba omo odun metadinlogbon kan ti ao so siwaju wipe iwakiwa yii
nda abo bo oun lati ma ko arun kogboogun nii AIDS E je kia kilo fun
wipe gbogbo ibalopo laarin eleya ara kanna nipase atenubonu ma nse
okunfa arun kogbogun AIDS ni kiakia ati pelu irorun fun ore at ebi
ti
e ba ka iwakiwa yii mo lowo, e gbodo gba adura fun gidigidi lehin
opolopo ibawi, kie si mu iru eni bee lo si iwaju awon eni olorun fun
itusile ninu igbekun iwakiwa yi.
Awon oyinbo alawo funfun tile ma npa iro funfun wipe abimo ni iwa yi
je fun awon eniyan kan. Ogoro eniyan n wu iwakiwa yii ni ipase olaju
ati idaamu okan tin se adina gboku fun igbogun ti iwakiwa yii.
Iwakiwa le di ohun igbagbe pelu adura ati ohun ija lati inu emi. Eyi
ni ona kan soso gege bi ose ti awon ese nlanla tio ku. Ibalopo
Okunrin si Okunrin yii je nkan to lewu pupo gege bi “se”
Gbogbo iwe ijoba ati adani gbodo ko awon akeko won lati lodi si iwa
yi. Won gbodo se ofintoto lati mu iwakiwa yii laarin ile-iwe ati
ibugbe awon akeeko wa gbogbo.

Ni ipari, mo gbagbo wipe isoro ti n koju ebi gbogbo ni orile ede yii
ni ibalopo Obinrin sobinrin. Emu wa si Ero oko tio fe iyawo ti nwu
iwakiwa yii pelu ore re laihan si oko re (ti o n kigbe wipe kosi
okunrin ti loe temi lorun) Iru aya wo ni eyi je, Iru iyawo wo ni yio
ya? Nje koni mo ko awon omo re ni iwakiwa yi pelu apeere eyi ti asa
ati ise ile alawodudu ko fowo si.

Olorun nife orile ede yii. Olorun nikan ati adura gbogbo eniyan
orile
ede yii ati atunbi awon tio ti se agbako iwakiwa yii nikan lole gba
orile ede yi lowo idaamu apanirun igbehin yi, mo joko nile itawe
omolehin Jesun kan ni Ibadan tio nta nkan mimu ibile kan ti a pe ni
zobo bakanna ni bi mo ti gbadun oun mimu yi ni mo sa deede ri iwe
iroyin awon kirisitieni (Family Encounters) kan pelu akole
yii ” Ibalopo Obinrinsobinrin ni ibi gbogo wan”
“Lakiriboto go de”. Obi gbodo Ji giri.
Mon sokun bi mo ti nka Ibalopo aileto yii pelu eto ni ile iwe
alakobere ati giga pelu iranlowo awon oluko koda ni igbamiran pelu
olori ile iwe ni pa mimu awon omo kekere wo egbe buburu yii
lorekore.
Awa iya orile ede yii gbodo ji giri si ija ati wa egbo dekun fun
iwakiwa yii, eyi ti o mo ju ninu awon ogun mimo lati da aabo to peye
bo awon ogo were wa.

73 Responses to “IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI!”

 1. American Stuff Says:

  I like how you link your pages together.

 2. Afolabi Says:

  I just try Omo Ogun to search for Nigerians and i found this am very happy and i will want you to please visit my web page. I am a young graduate nigeria who out of unemployment design jobs for myself and others but i can’t do it alone i nees support, i love to put smile on peoples’ face as that is my passion. The government can not help everybody not even when we are in PADY PADY government with alot of discriminations here and there on who is a university graduate and a polytechnic graduate and they don’t want crime but they forgot that an idle hand is the devils’ work shop. please send this to as many that can help us get a job of the one on that web or support our vision. Naija o ni baje o, Amin o.

 3. olarewaju yunis Says:

  i wish u best of luck

 4. Raji Bolaji A Says:

  Well dis is not a surprise to me bcos most people all over d world is practising leibilianism act not even nig alone so i will government and d public sector to help introduce dis into primary,secondary and tertiary education so dat they wil knw d danger in it and morealso they job for our people and if dis is done there wil b no thief and leibilialism act bcos if nothing like dat people in a peaceful life Frm ADEYEMI COLLEGE OF EDUCATION ONDO PHYSIC DEPT

 5. Yeye Akilimali Funua Olade Says:

  Raji Bolaji A,We will fight this disease in Nigeria. Get on the Nigerian sites and sound off about it. Have a prayer point against this evil sin. Write articles warning people on it! Olodumare will help us make Nigeria homosexual free! Keep up the fight agst it and pray about it and we will overcome it!

 6. Bayo Olade Says:

  The problem we have in Nigeria that is causing homosexuality and lesbianism may be regarded as an advanced form of illiteracy. Monkey see monkey do. Due to the influx of porn videos and the introduction of the internet, low grade mental people see sexual acts and feel it is the way things are done in the western world. They feel that by copying these acts, they are being mordern. They always like to show that they too are advanced by doing things that are being practiced in advanced countries. The education required to bring Nigeria back from the brink is out of this world.

 7. Raji Bolaji A Says:

  Let fight disease together so we can achieve something at d end of d day bcos dis lesbiliasm act is like a disease which spread all over d universe and d best way is to eradicate by aving talk to tall wit people on mass media or any other communicative agent and tell people d danger in it

 8. Raji Bolaji A Says:

  Iyaafin yeye olade, i wil be happy if u can give me ur contact no and address so dat we could discuss together bcos i love dis kind of article and my no is 08068673298 pls, it’s serious u ave my no wit u and i ave urs so dat if there is anything i can use to help to lift dis article up maybe by contribute to d article i will not institate to do it.

 9. Raji Bolaji A Says:

  Here i come again & again wit my advice dis homosexuality & lesbianism of a thing wel dis thing is not something to everybody it is only bcos civilization dat ave change d whole thing entirely bcos if we trace it our forefather we discover dat nothing of such has never happen in suitation whereby d change has never know of any sexuality of a thing less he’s being hand over to someone in marriage but now civilization has made everything change even before d has reach maturity age is being practising d act of lesbianism so everything ave change and also in a suitation where a child is being expose different kind of immorality like allow to stay in a place where their parent is aving normal playing in d bed so all these can cause lesbianism. I wil argue our govt and public sector to pls and pls fight against dis lesbianism. Your for ever RAJI BOLAJI A (ADEYEMI COLL OF EDUC ONDO) PHYSICS DEPT

 10. Ajayi Zenami Temilade Says:

  E n le gbogbo ile ooooooooo. Ero temi nipa awon ohun ti o n se okunfa iwa ibaje yii ko ju olaju alasodi ti awon eniyan ti o n kopa nini iwa naa ni. Awon Yoruba bo , won ni,’Bi ara ile eni ba n je kokoro ti o dara ti a ko ba so fun-un, kurukere re ko ni je ki a sun lale’. Ona abayo ti emi ro wipe o wa fun-un ni wipe ki ijoba apapo wa nnkan se si awon ibi ti won ti le maa ri awon aworan nipa re wo lori ero ayelujara(internet).
  Lona keji, ki ile igbimo asofin agba ni orile-ede yii se abadofin ifiyajeni fun awon ti won ba ka iru iwa bayii mo lowo ati awon arufin.
  Eketa ni wipe ki ijoba ile yii se ofin fun ayewo finifini lori awon aworan agbelewo ti won ti ilu okeere wa ati awon ti o n jade.
  ESE PUPO

 11. Yoruba Minbar Says:

  NJE GBOGBO WA NI A FE DI OLORIIRE BI? TITI TI E O FI DI ENITI O SE ORIIRE JULO WOLE SI….http://www.yorubaminbar.com

 12. Yoruba Minbar Says:

  KINNI OHUN TI A NPE NI AGBOYE IJOSIN NINU ESIN ISLAM?
  http://yorubaminbar.com/HomeDetails.aspx?id=19&M=5

 13. oluleke Says:

  i need porn

 14. oluleke Says:

  hi; yeye

 15. Ifeco Says:

  Se ibalopo na dara ni

 16. poly2009@rocketmail.com Says:

  Oluleke kilofefi porn se?

 17. adejare tunde ojo Says:

  NI iWOYE TEMI ADURA LA MA GBA

 18. oyekunle Says:

  gbogbo awon nkan wonyi fi ye wa pe opin aye ti de tan o

 19. M B A Says:

  Opin aye tide nigba ti aba tii
  ri iru gbogbo iwa yii, ki obirin ma ba obirin ni asepo.
  ayafi ki olohun kowa yo o. amin

 20. Babatunde Says:

  Awa o nife si ibaje yi ni tori iwa osi n la ni afiki oloun o ma sanuwa

 21. Akeem salami Says:

  When:oun ti emi moni wipe opin aiye ti de tan,tori ti kiba sebe ni’ eyin na eti ara awon obirin olomoge towa laye nisin wo nkan toun sele lakoko, aso iwokuwo awon ni iru ise kuse awon ni sokoto buruku ni wiwo awon ni oju itokuto awon ni idi sisile awon nani,papanbari egbe baba won ni won ngbe kiri nitori afeaye, won si tun wa oko toma fewon sile abi eri iru igbesi aiye tiwon ngbe, ju gbogbo elo, awon ta won obirin wa isinyi loburu julo afiki olohun mafi gbogbo nkan won yi se idajo lewa lori ni o atokunrin ati obirin wa bibe koo,mio ro wipe enikan ninu wa leri ijoba orun woo ayafi awon malaika re ati awon anabi re nikan,ki olohun oran wa lowo lorile aiye yi nio odabo.

 22. Olawale Abdl Semiu Says:

  Awon obi nikan ni momo ti won le koko bawa mu iwa ibaje kuro siwaju ki awon Omo tolosi ile eko, inmean primary education if dis can occurs, as first step iwa ibaje is going limit in our societies

 23. Isaac Says:

  bien

 24. Olalude damilola Says:

  Olorun olodumare a fun awon ara adari wa ni ogbon lati le deku iwa ibaje lorile ede wa

 25. Max Browy Says:

  What you posted made a ton of sense. However, think on this, what if you typed a catchier title?
  I mean, I don’t wish to tell you how to run your website, but what if you added something to maybe get folk’s attention?
  I mean IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI!
  | BLACK IS BEAUTIFUL! is kinda boring. You could glance at Yahoo’s home page and note how they create article titles to get people to open the links. You might add a video or a related picture or two to grab people interested about what you’ve got
  to say. Just my opinion, it could make your website a little bit more interesting.

 26. water filters for the home Says:

  Hello this is kind of of off topic but I was wondering if blogs use
  WYSIWYG editors or if you have to manually code with HTML.

  I’m starting a blog soon but have no coding expertise so I wanted to get advice from someone with experience. Any help would be greatly appreciated! Cheers!

 27. Janelle Says:

  Great blog right here! Also your site a lot up very
  fast! What host are you the usage of? Can I am
  getting your associate link for your host? I wish
  my website loaded up as quickly as yours lol

 28. Find Out More About Save On Airfare Secrets Here Says:

  Very energetic blog, I liked that bit. Will there
  be a part 2?

 29. Olusegun Osho Says:

  E Ku ise takun takun.amin igbakehin ni eyi.emi asodi si Kristi ti bere si n sise.e je ka mura sile fun Bibo Jesu

 30. Ogundipe olalekan Says:

  Otitoni iwa yi po larin awan odo ati akeko, eyi fihan pe opin aye ti de, afi ki ha kun fun adura ki a si man iru ore ti ahun barin.

 31. Veda Says:

  I’ll immediately snatch your rss feed as I can’t find your e-mail subscription
  link or e-newsletter service. Do you’ve any? Please allow me recognize in order that I could subscribe.
  Thanks.

 32. timcrane Says:

  ogede nbaje…. ? mo sebi asa olaju ti so pe ka mase ba omo wi bi won ba nse ibaje ni? ki lo fa ariwo? niwon igba ti ko ba sonibawi, akebaje lomo yooda, iru asakasa bayi o si nile wa koto di 1981, abi nigbati gbogbo yin so pe olaju le nfe nko en eh? ere olaju naa niyen! bi obirin ba nfe obirin,mo rope ara eto women libration ni. bi obirin ba nfe ara won iyen ko pariwo,kiwon o lo sibi ti aaye o ti gba won ni. sebi obirin nfe okunrin nile yi,? nile adulawo, se oko lo ngbeyawo ni, abi iyawo lon gboko? o ti to gee,omo lefi!

 33. olumide Says:

  iwa ibaje nibi gbogbo…

 34. Moruff Abubakar Says:

  Awon omo olowo,alagbara,onipo nla ni orile ede naijiria ni won nba pade ninu iwa palapala wonyi,ti igbese ba waye lati fiya je enikeni ti a ka iru iwa bayi mo lowo: e o ri awon ti won o yoju pe awon lawon ni iru omo bee’ ko wa si nkan to faa bi ko se wipe owo pelu esu 5/6 niwon. ojo ti olowo ti ni owo re ni esu papaa ti nse budget iye ti oun maa na ati ibi ti oun maa na si lodoodun,awon olowo naijiria ko nii je ki igbese yi seese. Igbayen olopa pelu looya yi o maa fun won ni ofin to tu won to de won lori oro naa. Te,i nipe ki olorun gbe ija ara re

  • IDOWU TIMOTHY OLUREMI Says:

   lodo temi,nibikibi lorile agbaye,lodeoni emi-esu londari ihuwasi awon omo eniyan, kosese bere, lati odun 1990. niwa yi tin bere, oti waa gbile deledoko bayi,awon to si ko asa naa wa ti ku tan,owo awon to jogun e loku si,eyin to fe laju ti ko fo, ewo bi e baye je de,

 35. order adiphene Says:

  If you have been feeling tired and rundown lately, and seem to be gaining weight for no apparent reason, then it is time for a change.
  There are hundreds to choose from, allowing you the choice of matching
  the type with your own health and fitness goals. There is a section to discuss the biggest loser show,
  specific diets, and much more.

 36. adiphene best price Says:

  Not because they will be changed into adipose tissue, but because
  excess protein in your diet causes you to burn more protein and stare more fat.
  Glucomannan has a particular means to soak up water and swell inside the stomach.
  Note that you can only buy Adiphene online as they aren’t
  available in stores.

 37. Abiola Says:

  mo nife eleyi, eje ki a gbe asa ati ede yoruba laruge… oun a ni la naani

 38. Mr Matthew Says:

  Ibalopo obinrin sobinrin lopa Ilu sodomu ati gomora run…

  ki Olorun fun raare dasi pro iwa kiwa yii..
  amin

 39. Home Office Furniture Says:

  Good post. I’m experiencing a few of these issues as well..

 40. Quinton Says:

  In spite of my increasing irritation each individual time I run out of
  life and the feeling of falling more and more behind, I have become ever more
  knowledgeable of the advantages of enjoying this match.
  The most up-to-date scenario is Can in actuality Swamp, and the software gives
  you the entire qualities take into consideration in the sport to some handsome rush-inducing 425.

  Whilst this may possibly not appear extremely hard, Sweet Crush degree 76
  introduces you to an solely new problem: transporters.

 41. Ajibawo seun Says:

  A olorun gba wa oooo

 42. AWWALTOBILOBA Says:

  mo fe je ki ewa eto lori bi asense ogi baba ni ile yoruba

  • IDOWU TIMOTHY OLUREMI Says:

   mo dupe pupo,fun ipe lati wa si ipade idanile-ko bi won sense ogi baba ni ile yoruba.a dupe e see pupo.

 43. Oladejo taofeek Says:

  Iwa ibaje ni ki omobirin ma ba omobirin egbe re sun maa fi asiko yii be awon obi ki won mu oju to awon omo won

  • IDOWU TIMOTHY OLUREMI Says:

   l will continue saying this,the end time that predicted has come! take or leave it! since our women want equa-lity with men n no body see what is bad in that, if women now marry themselfs, why the noise,let see how far they will go! l can’t shout!(bi ileke o ba ja sile,e je ko ja sode! kannakanna ja toun to wu!)emi o ma le pari wo!

 44. Tawanna Says:

  The White House has released another of its health care reform clarification emails— there will be more.
  Brain Storm: A fun and interactive feature from
  the New Scientist website to discover which parts of the brain are maturing during adolescence and how this
  maturation can explain some unique adolescent behaviors,
  such as risk taking and morning lies in. Only aspirin-users reaped the brain benefits, the tests showed.

 45. Mark Dubowitz Says:

  Mark Dubowitz

  blog topic

 46. tranny Says:

  You created some decent points there. I looked on the internet for the issue and found most individuals is going as well as along with your website.

 47. Virgin Islands Says:

  This is a really good tip especially to those new to
  the blogosphere. Simple but very precise info… Thank you for sharing this one.
  A must read post!

 48. negocio Says:

  Please let me know if you’re looking for
  a writer for your blog. You have some really great posts and I feel I would be
  a good asset. If you ever want to take some of the load off, I’d really like to write some content for your blog
  in exchange for a link back to mine. Please shoot me an e-mail
  if interested. Cheers!

 49. Backlinks Says:

  A fascinating discussion is definitely worth comment.
  There’s no doubt that that you should write more about this issue, it may not be a
  taboo subject but usually folks don’t speak about such subjects.

  To the next! Cheers!!

 50. Lollapalooza Festival Says:

  What’s up, yeah this piece of writing is really nice and I have learned lot of
  things from it concerning blogging. thanks.

 51. Half Time Full Time Says:

  Hi to every one, as I am in fact keen of reading this website’s post to be updated regularly.

  It contains nice material.

 52. getting fit at 50 Says:

  An impressive share! I have just forwarded this onto a
  friend who has been doing a little research on this.
  And he in fact bought me breakfast due to the fact that I discovered it for him…
  lol. So let me reword this…. Thank YOU for the meal!! But yeah, thanx
  for spending the time to discuss this topic here on your website.

 53. sharing network Says:

  It’s hard to find educated people for this topic, however, you
  sound like you know what you’re talking about! Thanks

 54. porno Says:

  Thanks for sharing your thughts on mature. Regards

 55. 95Rory Says:

  Hello admin, i must say you have hi quality posts here.
  Your blog should go viral. You need initial traffic only.
  How to get it? Search for: Mertiso’s tips go viral

 56. resistance band hip mobility Says:

  Hey very nice website!! Guy .. Excellent .. Wonderful ..
  I’ll bookmark your web site and take the feeds also? I’m satisfied to
  find so many useful info right here within the publish, we need develop
  extra strategies in this regard, thank you for sharing.
  . . . . .

 57. photoshop tricks Says:

  Hi there, I would like to subscribe for this weblog to get newest updates,
  therefore where can i do it please help out.

 58. The SOFTWARE is supplied "AS IS". GSA disclaims all warranties Says:

  Awesome things here. I’m very satisfied to see your post.
  Thanks a lot and I’m taking a look ahead to contact you.
  Will you please drop me a mail?

 59. mozambique Says:

  Hello, i think that i noticed you visited my site thus i came to go back the prefer?.I am trying to to find issues to enhance my website!I assume its ok to make use of
  some of your ideas!!

 60. M字ハゲ以外にも効くプランテル Says:

  一般的に、薄毛改善には、その人のヘアサイクルのサイクルを通常の状態にする事が重要です。だからこそ、毛母細胞の分裂回数をいち早くストレスのない状況にするのが最大に大切だと考えられています。

 61. healthy lifestyle Says:

  What i don’t understood is in truth how you’re no longer really a lot more
  neatly-preferred than you might be now. You’re very intelligent.

  You understand thus significantly in relation to
  this matter, made me in my opinion imagine it from a lot of various angles.
  Its like men and women aren’t interested until it is something to
  do with Lady gaga! Your individual stuffs outstanding.
  At all times take care of it up!

 62. AdultFrinendFinder Says:

  At this time it appears like Movable Type is the best blogging platform available right now.
  (from what I’ve read) Is that what you’re using on your blog?

 63. flecxy boy Says:

  My own word is not more if a man not have enything in this live no body we ear what the person is saying I can say anything naw I just belg you people suld help me now that what I say good lock

 64. Ways To Save A Relationship Says:

  Ways To Save A Relationship

  IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI! | BLACK IS BEAUTIFUL!

 65. Business life Says:

  Business life

  IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI! | BLACK IS BEAUTIFUL!

 66. Going at www.jiadianol.com Says:

  Going at http://www.jiadianol.com

  IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI! | BLACK IS BEAUTIFUL!

 67. Salusproject.Eu Says:

  Salusproject.Eu

  IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI! | BLACK IS BEAUTIFUL!

 68. Dating packages Says:

  Dating packages

  IBALOPO OBINRIN SOBINRIN NI ORILE EDE NAIJIRIA IYALENU EETIRI! | BLACK IS BEAUTIFUL!

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s


%d bloggers like this: