Archive for December 29th, 2006

TIWANTIWA:JOIN NOW AND LEARN YORUBA!

December 29, 2006

Tiwantiwa
Home
Messages
Post
Polls
Info
Settings

Group Information
Members: 137
Category: Yoruba
Founded: Dec 25, 2004
Language: Other
Group Settings
Restricted membership
Unmoderated
All members can post messages
Email attachments are not permitted
Members cannot hide email address
Listed in directory

Yahoo! Groups Tips
Did you know…
You can send a message to the group from the Web site?
Yahoo! 360°
Publish a blog and share your photos and interests with who you like. Create your own 360° page now.

NEW Yahoo! 360° – Your one place to Express, Share and Discover. Share photos and your blog with your group.
Home

Activity within 7 days:1 New Message

Description

Egbe Yahoo! fun isoji, igbega ati itankale ede Yoruba. Ede aladun yi nikan ni awa ti a wa ninu egbe yi yio maa ko si ara wa. A ko fe Geesi, Faranse tabi edekede, bikose Yoruba.

Awon omo Yoruba nikan ko ni egbe yi wa fun. Gbogbo awon ti o feran ede Yoruba, ti won si fe ilosiwaju re, ni a pe lati ba wa dapo. Ibikibi ti o wu ki e ti wa, niwon’gbati e ba ti setan lati ba wa soro ni ede Yoruba nibiyi, a ki yin ku abo.

Yoruba dun un so!

Aworan: Opa Oranmiyan, Ile-Ife – © Molara Wood, 2004. Pelu ase lati owo ayaworan.
Most Recent Messages (View All)
(Group by Topic) Search: Advanced Start Topic
e pele si gbogbo e ku odun keresimesi
e pele mo ireti gbogbo ni e ku odun keresimesi alaafia. Okan
Posted – Sun Dec 24, 2006 10:55 am tws9718
Send IM
Send Email
Invite to Yahoo! 360°
Re: AKEDE AGBAYE:IROYIN OTITO FUN GBOGBO OMO YORUBA,OJOBO,OJO MEJE,O
Yeye, Eseun. Nje etiri [r.r.m] awon aworan yin ti mo fi ran nse? Abolore Kiye si: Odidere [r.m.r.m] eye okun [d.r.], Aluko [d.d.d] eye osa [d.d.]; ti oba je
Posted – Sat Dec 16, 2006 12:30 pm Abolore Folorunso M
fm_moshood
Offline
Send Email
Invite to Yahoo! 360°
AKEDE AGBAYE:IROYIN OTITO FUN GBOGBO OMO YORUBA,OJOBO,OJO MEJE,OSU
SO; EFCC N WA TINUBU GIDIGIDI!! WON KO AWON OGA ILEESE OWO LO SATIMOLE OHUN TAWON ARAALU N SO NI PE TINUBU GANAN NI EFCC N WA BI WON SE MAA MU NITORI AJOSEPO
Posted – Sat Dec 16, 2006 11:50 am Iyaafin Yeye Akilimal…
yeyeolade
Offline
Send Email
AKEDE AGBAYE:IROYIN OTITO FUN GBOGBO OMO YORUBA,OJOBO,OJO MEJE,OSU
SO; EFCC N WA TINUBU GIDIGIDI!! WON KO AWON OGA ILEESE OWO LO SATIMOLE OHUN TAWON ARAALU N SO NI PE TINUBU GANAN NI EFCC N WA BI WON SE MAA MU NITORI AJOSEPO
Posted – Sat Dec 16, 2006 11:41 am Iyaafin Yeye Akilimal…
yeyeolade
Offline
Send Email
E ba wa fimo kunmo: Wikipedia Olosoose
Mo juba Eyin Agbaagba o. Mo woye pe o to akoko lati fi to wa leti pe loju/ninu itakun agbaye, a ni anfaani lati ko ero wa han faye, tabi lati se atunse si
Posted – Thu Dec 14, 2006 5:21 am adeola faleye
adefaleye2004
Offline
Send Email
Invite to Yahoo! 360°

Message History
Jan Feb Mar Apr May Jun Jul Aug Sep Oct Nov Dec
2006 87 48 82 68 98 28 41 15 17 33 25 51
2005 93 124 89 115 90 62 129 117 99 86 81 201

Resources
Post message: Tiwantiwa@yahoogroups.co.uk
Subscribe: Tiwantiwa-subscribe@yahoogroups.co.uk
Unsubscribe: Tiwantiwa-unsubscribe@yahoogroups.co.uk
List owner: Tiwantiwa-owner@yahoogroups.co.uk

YAHOO! SPONSOR RESULTS
Read the Body Language of an Aggressor – Nightingales Training Services offers staff training courses in diffusion skills. Learn to read body language and recognize the signs of increasing aggression.
nightingales-training.co.uk

——————————————————————————–

Copyright © 2006 Yahoo! UK. All rights reserved.
Privacy Policy – Terms of Service – Guidelines – Help


%d bloggers like this: