TIWANTIWA:JOIN NOW AND LEARN YORUBA!

by

Tiwantiwa
Home
Messages
Post
Polls
Info
Settings

Group Information
Members: 137
Category: Yoruba
Founded: Dec 25, 2004
Language: Other
Group Settings
Restricted membership
Unmoderated
All members can post messages
Email attachments are not permitted
Members cannot hide email address
Listed in directory

Yahoo! Groups Tips
Did you know…
You can send a message to the group from the Web site?
Yahoo! 360°
Publish a blog and share your photos and interests with who you like. Create your own 360° page now.

NEW Yahoo! 360° – Your one place to Express, Share and Discover. Share photos and your blog with your group.
Home

Activity within 7 days:1 New Message

Description

Egbe Yahoo! fun isoji, igbega ati itankale ede Yoruba. Ede aladun yi nikan ni awa ti a wa ninu egbe yi yio maa ko si ara wa. A ko fe Geesi, Faranse tabi edekede, bikose Yoruba.

Awon omo Yoruba nikan ko ni egbe yi wa fun. Gbogbo awon ti o feran ede Yoruba, ti won si fe ilosiwaju re, ni a pe lati ba wa dapo. Ibikibi ti o wu ki e ti wa, niwon’gbati e ba ti setan lati ba wa soro ni ede Yoruba nibiyi, a ki yin ku abo.

Yoruba dun un so!

Aworan: Opa Oranmiyan, Ile-Ife – © Molara Wood, 2004. Pelu ase lati owo ayaworan.
Most Recent Messages (View All)
(Group by Topic) Search: Advanced Start Topic
e pele si gbogbo e ku odun keresimesi
e pele mo ireti gbogbo ni e ku odun keresimesi alaafia. Okan
Posted – Sun Dec 24, 2006 10:55 am tws9718
Send IM
Send Email
Invite to Yahoo! 360°
Re: AKEDE AGBAYE:IROYIN OTITO FUN GBOGBO OMO YORUBA,OJOBO,OJO MEJE,O
Yeye, Eseun. Nje etiri [r.r.m] awon aworan yin ti mo fi ran nse? Abolore Kiye si: Odidere [r.m.r.m] eye okun [d.r.], Aluko [d.d.d] eye osa [d.d.]; ti oba je
Posted – Sat Dec 16, 2006 12:30 pm Abolore Folorunso M
fm_moshood
Offline
Send Email
Invite to Yahoo! 360°
AKEDE AGBAYE:IROYIN OTITO FUN GBOGBO OMO YORUBA,OJOBO,OJO MEJE,OSU
SO; EFCC N WA TINUBU GIDIGIDI!! WON KO AWON OGA ILEESE OWO LO SATIMOLE OHUN TAWON ARAALU N SO NI PE TINUBU GANAN NI EFCC N WA BI WON SE MAA MU NITORI AJOSEPO
Posted – Sat Dec 16, 2006 11:50 am Iyaafin Yeye Akilimal…
yeyeolade
Offline
Send Email
AKEDE AGBAYE:IROYIN OTITO FUN GBOGBO OMO YORUBA,OJOBO,OJO MEJE,OSU
SO; EFCC N WA TINUBU GIDIGIDI!! WON KO AWON OGA ILEESE OWO LO SATIMOLE OHUN TAWON ARAALU N SO NI PE TINUBU GANAN NI EFCC N WA BI WON SE MAA MU NITORI AJOSEPO
Posted – Sat Dec 16, 2006 11:41 am Iyaafin Yeye Akilimal…
yeyeolade
Offline
Send Email
E ba wa fimo kunmo: Wikipedia Olosoose
Mo juba Eyin Agbaagba o. Mo woye pe o to akoko lati fi to wa leti pe loju/ninu itakun agbaye, a ni anfaani lati ko ero wa han faye, tabi lati se atunse si
Posted – Thu Dec 14, 2006 5:21 am adeola faleye
adefaleye2004
Offline
Send Email
Invite to Yahoo! 360°

Message History
Jan Feb Mar Apr May Jun Jul Aug Sep Oct Nov Dec
2006 87 48 82 68 98 28 41 15 17 33 25 51
2005 93 124 89 115 90 62 129 117 99 86 81 201

Resources
Post message: Tiwantiwa@yahoogroups.co.uk
Subscribe: Tiwantiwa-subscribe@yahoogroups.co.uk
Unsubscribe: Tiwantiwa-unsubscribe@yahoogroups.co.uk
List owner: Tiwantiwa-owner@yahoogroups.co.uk

YAHOO! SPONSOR RESULTS
Read the Body Language of an Aggressor – Nightingales Training Services offers staff training courses in diffusion skills. Learn to read body language and recognize the signs of increasing aggression.
nightingales-training.co.uk

——————————————————————————–

Copyright © 2006 Yahoo! UK. All rights reserved.
Privacy Policy – Terms of Service – Guidelines – Help

48 Responses to “TIWANTIWA:JOIN NOW AND LEARN YORUBA!”

 1. Alhaji Lukman Agbefawo Says:

  E ku dede iwoyi.
  Inu mi dun gidi gidi lati ri igbinyanju ti ense lati le mu ede yoruba gbenle lagbaye.

  Mon fi asiko yi ki gbogbo omo kaaro ojuree pe olorun a wa pelu wa, ati olootu eto yi owo yin a ma roke.

  Emi ni ti yin toto
  Alhaji Agbefawo
  Lati Cotonu

 2. Reveal Me The Secret Says:

  Very interesting post there! Keep-up the great work…

 3. Lynn Says:

  Ago o,

  Mo fe ko Yoruba.

  Ekasan

 4. kolapo oresile Says:

  EKU IGBADUN ASIKO YI.INU MI DUN LATI RI IBI TI MO TI LE BA AWON OMO KAARO OJIRE SORO, MO SI LERO PE ELE FI

 5. james allen bressem Says:

  life is a war of unification delegated by gravity the power of God.

  read the full truth:
  http://www.geocities.com/wizardofwizards/gsm.txt
  http://www.geocities.com/wizardofwizards/gsm.gif
  http://www.geocities.com/wizardofwizards/gsm.ppt

 6. Akinfe Moses Boluwaji Says:

  Mo fe owe “ise ni ogun ise..”

 7. kehinde Says:

  eku dede izoyi kehinde ni oruko ,i lati ivory coast abidjan adjame temidire orita orelope transport nigeria si abidjan nje mo le ri zeb site ti mo fi le mo gbo iroyin yoruba

 8. Oshun Fosupo Says:

  Deje la traducciòn de cada frace, libaciòn , o palabra.

 9. kola oresile Says:

  inu mi dun lati ri web site.

 10. Babatunde Adebayo Says:

  Eku Igbiyanju, Olorun yio tunbo ma so agbara d’tun, eku igbiyanju lori gbigbe ede yoruba laruge, Olorun yio ma fun yin se ooo. kaaro oojire agbe wa ooo. Emi ni tiyin tooto Babatunde A.K.

 11. Babatunde Adebayo Says:

  Eku Igbiyanju, Olorun yio tunbo ma so agbara d’tun, eku igbiyanju lori gbigbe ede yoruba laruge, Olorun yio ma fun yin se ooo. kaaro oojire agbe wa ooo. Emi ni tiyin tooto Babatunde A.K. (Omo Iwo Olo Oba, Omo ateni gbola ateni gbore)….

  From Okota, Lagos State

 12. Babatunde Adebayo Says:

  Ile ati Ede yoruba ko ni baje ooo. Emi ni tiyin tooto Babatunde A.K. (Omo Iwo Olo Oba, Omo ateni gbola ateni gbore)….

  From Okota, Lagos State.

 13. John Moxford Says:

  It is very easy to learn Yoruba.

 14. ibrahim Says:

  inu mi dun ti mo ba awon omo karo o jire soro lori ero yin

 15. ibrahim Says:

  mo sise ni laspotech ero ibani soro mi re 07041677366 mo si se mi bi kara ile ni agbegbe ikorodu ni mo gbe

 16. ibrahim Says:

  eni keni ti o ba fe ra ile ni agbegbe ikorodu ata ile plot abi acre e le pe mi si ori ero iba ni soro yi 07041677366 mo si se ni lagos state polytechnic

 17. John Moxford Says:

  I came across this information in the internet and it is worth looking at. There is a course available to teach yoruba, that can either be downloaded from the internet or bought as a CD.

 18. Adeniran Adenike Says:

  Mo ki yin lopolopo nipa igbelaruge ede abinibi (Yoruba) wa, ki a ma paro, aseyori gidi ni eyi je, o si tun je iwuri fun gbogbo omo Yoruba ni t’ile-t’oko. E ku ise opolo.

 19. Olusola Olokun Says:

  The world on information on Ikorodu, from its history to its giant strides of present day. Ikorodu town has all it takes to become on of the best locality in Lagos. … Check the info out at… http://www.omavo.com..

 20. Falilat Oladejo Says:

  e n le n be un eyin omo karo ojire, eku ise olorun yoo fun wa ni emi gigun

 21. Abiodun Says:

  Eku igbiyanju o, oduduwa a gbe gbogbo wa o, mo fe ki e bami ba gbogbo omo kaaro oojire toku soro lati tubo teramo siso ede babanla wa nibi kibi ti a ba wa, ka ma so ile nu, ki a ma ba so apo iya ko. Inu mi dun lati pade omo ilu mi nibi, awa ni omo IWO OLODO OBA, OMO ATENIGBOLA. Emi ni omo AGORO BOGUN BOLU.

 22. lattyphat Says:

  mo fe ko ede yoruba

 23. wasiu Says:

  mo ki awom omo yoruba ku ewuodun tuntun ti afe bo si ki olodumare sowa ju igba na.

 24. ramon owolabi Says:

  mo ki gbogbo eyin omo yoruba oduduwa a gbe wa o. amin

 25. QABIOLA Says:

  OMO YORUBA NI MI

 26. Ògúnsìmbò Adéolú Says:

  E sé púpò,gbogbo èyin tí e n se agbáterù irú àwon ànfàní báyìí,ojú ò ni yín tì lólá Èdùmàrè,àyúnlo-àyúnbò lowó n yénnu,e ò sì ní te ojú ilè mólè. Lólá Olórun, á júse fún wa o.Ire obáyìí,ojú ò ni yín tì lólá Èdùmàrè,àyúnlo-àyúnbò lowó n yénnu,e ò sì ní te ojú ilè mólè. Lólá Olórun, á júse fún wa o.Ire o

 27. Alamu kareem Says:

  Inu mi dun lati ri web site yii!. Nito ri’pe opolopo awon omo yoruba ni wan ko gbo ede yoruba., sugbon lati ipase eto ti egbe kaleyi won ti npada wasi ede abinibi wan. L’eekan si emini alamu kareem (omo onilogbo asowo, omo asolu sawo.)…..

 28. Alamu kareem Says:

  Apapo awa egbe youth organization, ti emi’sije oludasile egbe na. Inu mi dun lati ri web site yii!. Nito ri’pe opolopo awon omo yoruba ni wan ko gbo ede yoruba., sugbon lati ipase eto ti egbe kaleyi won ti npada wasi ede abinibi wan. L’eekan si emini alamu kareem (omo onilogbo asowo, omo asolu sawo,omo ekusere agbabo yeye)….. Fun ajosepo egbeyi epe mi ori ero 08081929631.

 29. yusuf wazeeu D. Says:

  i just lik

 30. muhyideenbello Says:

  iroyin tiwantiwa se koko fun oju lowo omo yoruba atata to ri na ni ofi wu mi pe kiun kegbe ni nu iroyin yoruba

 31. Oluwadamilare Says:

  Ojumo re si gbogbo omo yoruba, ase yori lama se o

 32. Aderibigbe Oludare Akeem Says:

  alatagba yi wa paa. Inu mi dun lati dara po mo atagba yii, nitori o fun mi ni anfaani ati ko edee abinibi mi si awon ti o yee yekeyeke.

 33. Tinuade Says:

  Ojutole ojutoko,ekuse o. E fun mi ni iroyin ti 2012

 34. Ola isa Says:

  Ki lo dun to ila alasepo Nigbati aba nfi ede yoruba ka iwe gba oye imo ijinle ninu ise ero ati iwosan. Yoruba tawon yo

 35. Egbewumi Adekunle Says:

  E ku dede iwoyi, a si ku oririn yii gbogbo kootu-a-a-jii-re bi, igba yi a san wa o, E ku ise asela.

 36. monete oro investimento Says:

  My partner and I stumbled over here by a different website and thought I may as well check things
  out. I like what I see so now i am following you. Look
  forward to looking over your web page yet again.

 37. Ohunx Says:

  keep it up

 38. htc Says:

  Great post. I was checking contantly this blog and I am inspired!
  Veery helpful information specially the remaining
  part 🙂 I maintain such information a lot.
  I waas looking for this certain information ffor a lonng time.

  Thanks and best of luck.

 39. Cream pemutih aman Says:

  Remarkable! Its truly awesome paragraph, I have got much clear idea concerning from this paragraph.

 40. Dr Sherri Worth Says:

  Dr Sherri Worth

  TIWANTIWA:JOIN NOW AND LEARN YORUBA! | BLACK IS BEAUTIFUL!

 41. ahmef Says:

  émo Ku ojumo’o omo naijiria salaafia le olohoun yo wa peluwa o Amin

 42. Olawale Oluwakayode Olambeloye omo Akinwale Says:

  Gbogbo eyin ojogbon ati oloye eniyan, omo Oodu Ateworo, ti e forikori, fimosokan, gbe irufe ate oyinbo (platform) yii sile lati pe ki awa omo kootu oojire, o lee maa gbo agboye (d.m.m), agboye (d.m.d) ati agboyanrannti (d.m.r.r.r.m) ijinle ede omo ojulowo kootu ojiire bi, item omo Yooba ojulowo: mo gb’osuba sadankata fun yin joo. E seun, e ku aigbagbe Ile, e ku ainijeki orirun Yooba ‘o parun. Eledua ko nii jeki site yin ‘o polukurumusu o. (Amin, ase, Edumare.)

  Ire o.

 43. soliu mutiu opeyemi Says:

  lnu mi dun lati se alaba pade iru itakun yi,akiyin aki yin oluwa yio mo wa pelu yin o

 44. call girls Says:

  Thanks a lot for sharing this with all people you really recognise what you’re speaking about!

  Bookmarked. Please also discuss with my site =). We may have a hyperlink
  change agreement among us

 45. hellen Says:

  mo nifesi ede yi ara mi lo

 46. chewing gum without aspartame Says:

  Good day! This post could not be written any better! Reading through this
  post reminds me of my old room mate! He always kept chatting about this.
  I will forward this post to him. Pretty sure he will have a good read.
  Thanks for sharing!

 47. Casino scams Says:

  It’s amazing in favor of me to have a site, which is beneficial in support of my experience.

  thanks admin

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s


%d bloggers like this: