OMO YORUBA O FE PA EDE YORUBA O! ADALU YORUBA KODA!

by

PublicMrs.Yeye Akilimali Funua Olade
LATI OWO AGBEJORO OLANREWAJU Sikiru Adewoye-
YEYE AKILIMALI FUNUA OLADE
Eri maa je mi n so.Akojopo oruko Yeye gbodo mu royiroyi okan wa nipa n’ibo la ti bi won.Ibi ti a ti bi Yeye ko ja bi ise Oodua ti won gbe l’owo ti iseda ati awon alale Ile Yoruba si n fun won se.
Oro asa ati ise Yoruba kii se awada rara fun omo bibi Amerika ti eje adulawo fi ago ara re se ibugbe.Ko si ohun to ba Yeye l’okan je bi amulu…mola ede Yoruba.Bi Yeye se tutu ni iwa bi adaba to, won ko ri ara gba adalu ede Yoruba ati Geesi.Ede Yoruba ponbele je won l’ogun jojo.
Yeye k’apa okanjuwa won nipa oro(wealth) ati yodoyodo aye.Ko r’oro bee ko r’aago.Igbagbo ninu adura ni igba iponju mu won duro sinsin ninu Olorun.Bee won ko fi esin Kristi t’ako isese ati orisa.
Iranti iwa amunisin ati eleyameya ilu abinibi won ti da ogbe adaajiina si Yeye l’okan.Ikorira naa ga.
Ayafi ti ojumo ko ba mo ni Yeye ko ni ko si t’oke t’ile ofi ati ileke oniruhunru bi ojo iyawo.Ti ide owo ni ka so tabi t’ileke orun?T’ibadi nikan ni n ko mo.
Awon elerokero tile ro wipe imura yi ba amodi wa ni.Amodi l’ara taani?Opolo Yeye t’ohun ojogbon Fasiti egbera ni.Agbekale ati irori Yeye se apeere Alosi(leftee) gege bi olopolo pipe.
Yeye kii se aniyan ola bee ko fi ife awo dudu pamo.Ana Yeye meteeta l’okunrin dudu bi koro isin ni.Ibalopo ako ati ako ohun abo pelu abo ko Yeye ni irira ju ipaniyan lo.
Yeye ni ife aisetan.Olojuaanu ati onirele okan “Akata” ni.Bee alaafia won p’eye.Leyin odun kerinlelogota, irin ibuso ogorun ko jo Yeye l’oju.Ko m’eya, ko m’esin.Yeye f’eran iwe iroyin alaroye ati Tiwa n Tiwa ni kika.Won a si tun ra bun eniyan fun akagbadun.
Ni akotan, onkowe, onkawe, agb’asaga, olutunu, atunluse, ajajagbara, abiyamo ati oluko ni Oludari Ile iselojo iwe nipa ogun ati iwadi Adulawo to t’edo si aarin gbungbun Aba Adeyipo, Igbo Elerin, Ibadan.
LikeUnlike · · Share · 28 minutes ago near Lagos
Mrs.Yeye Akilimali Funua Olade FOR “OMO DUDU AMERIKKKA” ‘S SAKE THIS IS AN APPRECIATION FOR ALL I AM DOING TO SAVE YORUBA LANGUAGE! AN AWARD CEREMONY IN NIGERIA HAS CHOSEN ME ALONG WITH TRUE GIANTS TO HONOUR FOR THIS IN NOVEMBER! I LOVE AFRICA! I LOVE YORUBAS! THEY ALWAYS SHOW APPRECIATION FOR PEOPLE WHO WANT TO BUILD,EVEN IF THEY THEMSELVES HAVEN’T TAKEN THE TIME TO DO SOME BUILDING!

Tags: , , , , ,

15 Responses to “OMO YORUBA O FE PA EDE YORUBA O! ADALU YORUBA KODA!”

 1. Antwan Says:

  I have heard that the name YORUBA translates to the word Israel. Does anyone know if this is true or not?

  • Ojoku Agbukebaoyorinsoro Says:

   This is not true, the word Yoruba comes from how the Hausa and other ethnic groups referred to us. Some of our traditional borderlands with the Hausa people were in areas that were natural borders from open plains to heavily dense forrest. So we were called the Yoruba meaning “they who live in the great wood.”

   • Antwan Says:

    Thank you for that information my brother. I am from the U.S. and I know nothing about what group I descend from. It could be the Yoruba. But now I study African history every single day. Because I believe that one day we will all be together again in the mother land. My heart longs to be there among my people.

 2. Antwan Says:

  I`m sorry, scratch my first question. I meant, Does the name Yoruba translate to the name Hebrew?

 3. Woli makinde sunday Says:

  Ile yoruba pelu asa,koye ki oparun,bee asa alasa koni bori ni ile yoruba,eje kajogbe yoruba laruge.

 4. bimbola Says:

  ise wa lodara ju,asa wa lo gbayi ju,eje ka ko omo wa ni pa isese,tori ise wa lodara ju

 5. BALOGUN TOYIN Says:

  I love Yoruba’s culture too much,if im oppourtune to come back to this world again,i will still prefer to b a YORUBA MAN

 6. Tunwagun Says:

  E ku u dede iwoyi gbogbo omo kaaro-ojiire,Oro mi ni pe eje ki a tun Ede,Asa,ati Ise Yoruba se ki Ésin ajeji ma ba bori wa!Yoo se e se o(Ase o)

 7. basheer akorede Says:

  ko si asa to dara to asa wa ni ile yoruba, owe yoruba lo so pe,naani naani ohun aba ni lanani

 8. Agboola john Says:

  Alaroye koni baje ooooo

 9. RAHEEM SULAIMAN JIMOH Says:

  IRAN, ATI EDE YORUBA LO DARA JU LAGBAYE.

 10. ojetoye tunji Says:

  olorun oba koni je ki ede yoruba parun

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s


%d bloggers like this: