OMO YORUBA! -OJO IBI MI-70TH-OCT.31ST- OMO MI E KI MI DAADAA!-NI FACEBOOK

by

Ara eba mi Kalo si Adeyipo ni Ilu Ibadan Lati ki IYA Mi IYA RERE, IYA DADA, IYA OLORIRE, IYA Malik, IYA Fabayo, IYA Olabisi, IYA Fehintolu, IYA Oluwasola. ABIYAMO TOTO,KU OJOBI, ASEYI SE AMODUN O, IGBA ODUN, ODUN KAN, ALAFIA ARA AMA JE YIN O, EMA JE OUNJE OMO PE, PE PE NI A GBARA OLORUN. AMIN……

akilimali_funua_220211

Fatoke Keji E Ku ojo ibi Yeye Akilimali. IYA daada, iya kan bi egberun…. Mo gbadura pe e o ni fi aisan lo eyi toku ninu Ojo aye yin (Amin)

Ibidun Adegbite Ilupeju Iya to mo iyi omo,igba odun odun kan.congratulations yeye Alikimali.

Mrs.Yeye Akilimali Funua Olade O SE O OMO MI DARADARA! A KARI O! ASE JESU!

1 min · Like

Mrs.Yeye Akilimali Funua Olade

October 31 at 9:50am ·

Tags: , , , , , , , ,

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out / Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out / Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out / Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out / Change )

Connecting to %s


%d bloggers like this: