BLACK PEOPLE OOO!YORUBA OOO!-IBEJI OOO!- FROM Voiceof YorubaYouth on Facebook

by

VOICE of YorubaYouth added 3 new photos — with Oladele Kehinde Foluso. Oriki Ibeji:
Wínrinwínrin lójú orogún
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀,
Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún,
Ẹdúnjobí,
ọmọ a gbórí igi rétẹréte,
Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá,
Ọ́bẹ́kíṣé bẹ́kéṣé,
Ó bé sílé alákìísa,
Ó salákìísà donígba aṣọ.
Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,
Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọmọ.
Bi Táyélolú ti nló ni iwájú,
Bééni, Kehinde ń tó lẹ́yìn,
Táyélolú ni àbúrò,
Kehinde ni ẹ̀gbọ́n,
Táyélolú ni a rán pé kí o ló tó ayé wò,
B’ayé dára , bi ko dára
O tó ayé wò,
Ayé dun bi oyin
Táyélolú, Kehinde, ni mo ki
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀
O dé ilé ọba térin-térin,
Jé kí nrí jé, kí n rí mú.
Orí mí jẹ́ ń bí ìbejì l’ọmọ,
èdùmàrè fún gbogbo àwọn tó ń w’ojú rẹ ní ọmọ gbajúmọ̀ bí ìbejì bí oooo… Àmín áṣẹ
See Translation
Oriki Ibeji:
Wínrinwínrin lójú orogún
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀,
Will ẹ̀jìrẹ́ ìṣokún,
Ẹdúnjobí,
G BO ỌMỌ SRI IGI MEADOW, ẹ layers
Remove nnn ọkàn méjì secrets but i wole míwá,
Ọ́bẹ́kíṣé bẹ́kéṣé,
Oh peace under skis by here sa,
Ó salákìísà donígba aṣọ.
Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,
Gbàdọ̀bálẹ̀ tíí lọ́wọ́ baba I mean secret lọmọ.
Would you even táyélolú nló iwájú,
Kehinde, bééni lẹ́yìn, nnn I
Táyélolú ni àbúrò,
Kehinde’s ẹ̀gbọ́n,
A burrito táyélolú ni pe sign o way I aye wò,
B ‘ Ayé Dara, bi ko dara
The tó ayé wò,
Ayé dun bi oyin
Táyélolú, Kehinde, ni mo ki
Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀
O de nt-Oba Terrin-Terrin,
Jé Nrí Jé Sign, sign n rí mú.
You do nnn orí ìbejì l ‘ Secret, ọmọ
Gbogbo àwọn èdùmàrè fun nnn w ‘ l law nï omo ojú gbajúmọ̀ ìbejì secret is secret… Àmín áṣẹ

https://m.facebook.com/voiceof.yorubayouth?fref=nf&refid=52&_ft_=qid.6286335489312891286%3Amf_story_key.1010596555994084283&__tn__=C

5 Responses to “BLACK PEOPLE OOO!YORUBA OOO!-IBEJI OOO!- FROM Voiceof YorubaYouth on Facebook”

  1. Patricia Mallory-Oduba Says:

    What BRILLIANCE!

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google photo

You are commenting using your Google account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

Connecting to %s


%d bloggers like this: