Archive for July 10th, 2021

BAYO ADEBOWALE O! – A TRIBUTE IN YORUBA O!

July 10, 2021

Òǹkọ̀wé tí ń fi èdè Gẹ̀ẹ́sì ṣe àgbékalẹ̀ ìtàn àṣà abínibí ni Ọ̀mọ̀wé Bayo Adebowale.
Méjì ni èmi ti kà nínú ìwé wọn kí n tó lọ ṣe àbẹ̀wò sí wọn ní oṣù tí ó kọjá. Ohun tí mo mú bọ̀ láti Adéyípo rè é. Kí Olódùmarè ó túbọ̀ dẹ́mìí àwọn àgbà alárògún sí fún àwa ọ̀dọ́ tí à ń kẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ wọn. Àṣẹ.

Èwo ni ẹ̀yin ti kà nínú àwọn ìwé wọ̀nyí ?

thankstodaddyBayoAdebowale

Proudofmyculture

Olùkọ́ńdúpẹ́ o!

©Bùkọ́lá R. Adélékè (2019)


%d bloggers like this: