Archive for the ‘YORUBAS BOOKS’ Category
December 9, 2020
Ọ̀JỌ̀GBỌ́N ỌLÁBÍYÌÍ BABALỌLÁ YÁÌ NÁÀ TÚN TI LỌ!
Ọjọ́ wo la ó mẹbọ ikú?
Ẹ dákun, ìgbà wo la ó mètùtù àlùmúútù?
Nígbà wo la ó le pinkú nípá?
Tíkú á sinmi fáàrí ìmẹ́ni wa.
Òkèèrè ni mo ti mọ Ọ̀jọ̀gbọ́n Yai,
Àmọ́ ẹ̀ẹ̀mẹtẹ̀ẹ̀ta tí a sọ̀rọ̀ ni wọ́n bá mi sọ̀rọ̀ bí i Baba sí ọmọ.
Bí Bàbá mi Diípọ̀ Fágúnwà àti ìyá mi Yinka Adeboye ti ṣe ròyin wọn gẹ́lẹ́ ni wọ́n rí.
Wọn ò kìí yẹ àdéhùn àfi bí ohun mìíràn bá fa ìdíwọ́, wọn yóò sì fi àyípadà náà tóni létí.
Wọn ò kì ń fojú kéré ẹni, bí wọ́n ṣe jẹ́ àgbà Ọ̀jọ̀gbọ́n tó, síbẹ̀ wọn ò níwà ìfojú panirẹ́.
Inú oṣù kẹrin ọdún yìí ni a jọ ṣe àdéhùn pé a ó rí ra bí wọ́n bá wá sí Naijiria.
Kòrónà ló yẹ àdéhùn tí n kò fi làǹfààní láti rí wọn mọ́.
Inú Oṣù Kẹfà ni wọ́n sọ pé kí n jẹ́ ká pa ọkàn pọ̀ sọ́dún tó ń bọ̀,
Ọ̀jọ̀gbọ́n Yai ní kí n máa ṣiṣẹ́ tèmi lọ a ó máa ríra lọ́dún 2021,
Òní ọjọ́ karùn-ún oṣù Kejìlá Ọdún 2020 lỌ̀jọ̀gbọ́n pàtàkì juwọ sáyé.
Èyí dùn mi wọnú eégún,
Ó kan mí lára wọnú bọ́ọ́gọ́,
Àìṣeémú ikú ló jẹ́ n gba kámú.
Kí Ọlọ́run ó tẹ́ wọn sí afẹ́fẹ́ rere,
Kí gbogbo ohun tí wọ́n fi sílẹ̀ ó má bàjẹ́ láṣẹ Èdùmàrè.
✍️Bùkọ́lá R. Adélékè (2020)
(Ìṣẹ̀dálẹ̀ Media Concept)
Like this:
Like Loading...
Tags:BLACK PEOPLE, YORUBA, YORUBA scholars, YORUBA WRITERS
Posted in AFRICA, AFRICAN MEN, AFRICAN WRITERS, AFRICAN WRITERS LIST IN YORUBA, YORUBA LANGUAGE, YORUBA LANGUAGE ARTICLES, YORUBA LANGUAGE IS DYING, YORUBA NOVELS, YORUBA WRITERS, YORUBAS, YORUBAS BOOKS | Leave a Comment »
March 11, 2013






ROM afrikannames.comAFRICAN WORDS FOR MOTHER”A mother cannot die.” -Democratic Republic of the CONGOEnjoy this list of African names.AKA (AH-kah). Mother. Nigeria (Eleme) FEKA (EH-kah). Mother earth. West Africa FINE -(EE-neh). Mother. Nigeria (Ishan) FIYA – YORUBA- MOTHERJIBOO (jee-boh). New mother. Gambia (Mandinka) FMAMAWA (MAHM-wah). Small mother. Liberia FMANYI (mahn-yee). The mother of twins. Cameroon (Mungaka) FMASALA (mah-SAH-lah). The great mother. Sudan FNAHWALLA (nah-WAHL-lah). The mother of the family. Cameroon (Mubako) FNANA (NAH-nah). Mother of the earth. Ghana FNANJAMBA (nahn-JAHM-bah). Mother of twins. Angola (Ovimbundu)NINA (NEE-nah). Mother. East Africa (Kiswahili) FNNENMA (n-NEHN-mah). Mother of beauty. Nigeria (Igbo) FNNEORA (n-neh-OH-rah). Mother loved by all. Nigeria (Igbo) FNOBANTU (noh-BAHN-too). Mother of nations. Azania (Xhosa) FNOBUNTU (noh-BOON-too). Mother of humanity. Azania (Xhosa) FNOLUNDI (noh-LOON-dee). Mother of horizons. Azania (Xhosa) FNOMALI (NOH-MAH-lee). Mother of riches. Azania (Xhosa) FNOMANDE noh-MOHN-deh). Mother of patience. Azania (Xhosa) FNOMPI (nohm-PEE). Mother of war. Azania (Xhosa) FNOMSA (NOHM-sah). Mother of kindness. Azania (Xhosa) FNONDYEBO (non-dyeh-boh). Mother of plenty. Azania (Xhosa) FNOZIZWE (noh-ZEEZ-weh). Mother of nations. Azania (Nguni)NOZUKO (noh-ZOO-koh). Mother of glory. Azania (Xhosa) FUMAYMA (o-MAH-ee-mah). Little mother. North Africa (Arabic) FUMI (OO-mee). My mother. Kiswahili FUMM (oom). Mother. North Africa (Arabic) FYENYO (yehn-yoh). Mother is rejoicing. Nigeria (Yoruba) FYEYO (yeh-YOH). Mother. Tanzania FYETUNDE (yeh-TOON-deh). The mother comes back. Nigeria (Yoruba) FYINGI (YEEN-gee). My beloved mother. NigeriaSent from my BlackBerry wireless device from MTN”Mama”(and Papa) were introduced into Yoruba language early by Yorubas who wanted to show they were educated, according Ojogbon Akinwunmi Isola.. So long ago that many think it is a Yoruba word! Now it has replaced -IYA almost completely! SO we must start using IYA instead and correct those who use it because word by word Yoruba is being replaced by english words killing the Yoruba Language! So do your part from today! We can and will SAVE Yoruba! Olodumare ase!
All Nigerian/AFRICAN Languages must learn from the mistake of educated Yorubas! DO NOT mix your Language! Reclaim your word for mother first for it is the most important word in any language!
“MAMA” must be replaced with the African word in your Language?
Like this:
Like Loading...
Tags:"MAMA" Is killing African words for MOTHER, mama, mother
Posted in ;YORUBA LITERATURE, AFRICA, AFRICAN A, AFRICAN AMERICAN WRITERS, AFRICAN AMERICANS, AFRICAN CULTURE, AFRICAN LANGUAGES, AFRICAN LANGUAGES ENDANGERED!, AFRICAN LITERATURE, AFRICAN LITERATURE IN YORUBA, AFRICAN MEN, AFRICAN POETS, AFRICAN PRESIDENTS, AFRICAN WRITERS, AFRICAN WRITERS LIST IN YORUBA, AFRICANS AMERICANS, AFRICANS IN AMERIKKKA, AKINWUNMI ISOLA, BACK TO AFRICA, BLACK BOYS .BLACK WOMEN, BLACK CHILDREN, BLACK CULTURE, BLACK MEN, BLACK MEN BLACK CHILDREN, BLACK NATIONALISM, BLACK PEOPLE, BLACK PEOPLE.AFRICAN AMERICANS, BLACK RACE, BLACK WOMAN, BLACK WOMEN, BLACK WOMEN WRITERS, BLACK WRITERS, BLACK YOUTH, blackpeople, BLACKS IN AMERIKKKA!, BLACKS IN CUBA, NIGERIA, NIGERIAN LANGUAGES IN YORUBA, NIGERIAN WOMEN, NIGERIAN WOMEN'S MAGAZINES, NIGERIAN WRITERS, SAVE YORUBA LANGUAGE, SAVING YORUBA LANGUAGE, THE BLACK RACE, TUNDE KELANI-GREAT YORUBA FILM MAKER, WRITERS, WRITINGS IN YORUBA, YORUBA, YORUBA CULTURE, YORUBA FILMS, YORUBA LANGUAGE, YORUBA LANGUAGE ARTICLES, YORUBA LANGUAGE IS DYING, YORUBA LANGUAGE IS DYING.YORUBA, YORUBA NOVELS, YORUBA WRITERS, YORUBAS, YORUBAS BOOKS | 2 Comments »
February 24, 2013
Tags:African Americans, enginering.Science
Posted in AFRICA, AFRICAN AMERICAN WRITERS, AFRICAN AMERICANS, AFRICAN LANGUAGES, AFRICAN LITERATURE IN YORUBA, BACK TO AFRICA:REALITY, BLACK CHILDREN, BLACK CULTURE, BLACK EDUCATION, BLACK GIRLS, BLACK MEN, BLACK MEN ARE BEING LYNCHED IN AMERIKKKA, BLACK MEN BLACK CHILDREN, BLACK PEOPLE, BLACK POWER, BLACK WOMAN, BLACK WOMEN, BLACK YOUTH, blackpeople, BLACKS IN AMERIKKKA!, BLACKS IN THE SCIENCES, LITERATURE, NIGERIA, NIGERIAN LANGUAGES IN YORUBA, NIGERIAN WOMEN, NIGERIAN WRITERS, NIGERIANS ARE THE SMARTEST PEOPLE IN THE WORLD, YORUBA, YORUBA CULTURE, YORUBA LANGUAGE, YORUBA LANGUAGE IS DYING, YORUBA LANGUAGE IS DYING.YORUBA, YORUBA WRITERS, YORUBAS BOOKS | Leave a Comment »
September 30, 2010
>
from yeyeolade.blogspot.com
Perspectives of Yorubaland: Compendium of Writings about Yoruba Arts and Culture
By Rotimi Ogunjobi
Perspectives of Yorubaland:
Compendium of Writings about Yoruba Arts and Culture
xceedia – tee publishing, 2010 – Art – 128 pages
if (window[‘_OC_autoDir’]) {_OC_autoDir(‘search_form_input’);}
|
if (window[‘_OC_reportEvent’]) { window[‘_OC_reportEvent’](‘summary’); }
We haven’t found any reviews in the usual places.
Contents
|
7 |
|
|
|
13 |
|
|
|
36 |
|
|
|
41 |
|
|
|
48 |
|
|
|
62 |
|
|
The Batá Drums
|
71 |
|
|
Common terms and phrases
.cloud9 {color: #7777cc;font-size: 10px;}.cloud8 {color: #6963CC;font-size: 10.5px;}.cloud7 {color: #6057CC;font-size: 11px;}.cloud6 {color: #574BCC;font-size: 11.5px;}.cloud5 {color: #4E3DCC;font-size: 12px;}.cloud4 {color: #4632CC;font-size: 14px;}.cloud3 {color: #3D26CC;font-size: 16px;}.cloud2 {color: #341ACC;font-size: 18px;}.cloud1 {color: #2B0DCC;font-size: 20px;}.cloud0 {color: #2200CC;font-size: 22px;}.cloud {margin-top: 4px;line-height: 24px;}.cloud a {margin-left: 3px;margin-right: 3px;text-decoration: none;}.cloud a:hover {text-decoration: underline;}
Bibliographic information
|
CLICK ON TO MY ARTICLE IN THIS BOOK HERE:
books.google.co.ke/books?isbn=9784983710…
Like this:
Like Loading...
Posted in AFRICAN AMERICANS, BLACK MEN, BLACK WOMEN, NIGERIA, YORUBA LANGUAGE IS DYING, YORUBAS BOOKS | Leave a Comment »